X
    Categories: News

LYRICS: Brymo – Olúmọ

Lyrics for Olúmọ by Brymo
DOWNLOAD AUDIO HERE
Mò n lọ sáké mo fẹ́ lọ rọ́jọ̀gbọ́n o
Mò n lọ sábéòkúta mo fé lọ rí
Ọmọ ṣóyínká
Oṣóyinká ooooo
Oṣóyinká
Oṣóyinká ooooo
Bẹ lọ sówu
Bẹ bá rárẹ̀mú o
Bẹ bá rí bába Ìyábọ̀, ẹ bá mi ki
Ẹbọra òwu
Ẹbọra òwu ooooo
Ẹbọra òwu, eh
Ẹbọra òwu ooooo
Bẹ lọ sábẹ́òkúta ìlú olúmọ
Bẹ bá ráláké ẹ bá mi ki
 
The post LYRICS: Brymo – Olúmọ appeared first on GL Trends.

admin :